A fope folorun yoruba hymn lyrics
A F’OPE F’OLORUN
A F’OPE F’OLORUN
- A f’ope f’olorun
L’okan ati l’ohun wa
Eni s’ohun ‘yanu
N’nu eni t’araye nyo
‘gbat’a wa l’om’owo
On na l’o ntoju wa
O si nf’ebun ife
Se ‘toju wa sibe. - Oba Onib’ore
Ma fi w asile laelae
Ayo ti ko l’opin
On ‘bukun y’o je ti wa
Pa wa mo n’nu ore
To wa, gb’a ba damu
Yo wa ninu ibi
L’aye ati l’orun - K’a f’iyin on ope
F’Olorun, Baba, Omo
Ati Emi mimo
Ti O ga julo lorun
Olorun kan laelae
T’aye at’orun mbo
Be l’o wa d’isiyi
Beni y’o wa laelae.
AFOPE F’OLORUN tonic solfa A13
s:- s s: l l- s :- :-
A f’ope f’olorun
s :- f: m r: m r :- d
L’okan ati l’ohun wa
s:- s s l: l s :- :-
Eni s’ohun ‘yanu
s:- f: m r: m r : -d
N’nu eni t’araye nyo
r : r r: m m: r :- :-
‘gbat’a wa l’om’owo
r: m fe :s: l: f: s :- :-
On na l’o ntoju wa
s: l s: f: m: f :- :-
O si nf’ebun ife
m: r: d: d: t d :- :-
Se ‘toju wa sibe.