OLOLUFE IWO LOKAN MI YAN LYRICS
Chorus: OLOLUFE IWO LOKAN MI YAN LYRICS
Ololufe iwo lokan mi yan
Iwo ni ma balo , titi ojo aye mi
Ololufe onitemi
Iwo ni ma balo titi ojo aye mi
×2
Verse 1
I have come to cherish you
Have come to love you
Have come to treasure you
For the rest of my days
Mofe ba olo, mofe maa sefeere
Together forever, forever together
Iwo ni mo fe, iwo lonitemi
Ade ori mi,oko mi
I call you my ancient of days
I call you the lord of my life
Mofe ba o lo, together forever
Verse 2
Kosohun tole yawa, moti sepinu, lokan mi,
lati mase feere,onitemi ololajulo
Mofe baolo,iwo ni mo feran julo,
mase fimisile lo olufemi owon
[Chorus]
Ololufe iwolokanmi yan Iwo ni ma ba lo Titi ojo aye mi Oloooolufe iwolokan miyan Iwo ni ma ba lo Titi ojo ayemi
Verse 3
Mafimisile lo, mofe fi iwa jo e baba
Tori enibini lanjo, je kin fi wa jo o
Mope o Larugbo ojo, Adagba ma paro oye
Iwo leni Mimo ti ‘n se Mimo, ti ‘n je Mimo
Ti ‘n gbe bi mimo
Download: Ololufe Mi Owon by Fola Moses Mp3 and Lyrics
Download Ololufe mp3 audio by Fola Moses