Orin 002 - Ife orun, alail'egbe
Oluwa fi igbala re be mi wo OD. 106:4 .
- Ife orun, alail'egbe,
Ayo orun sokale,
Fi okan wa se'bugbe Re,
Se asetan anu Re. - Jesu Iwo ni alanu
Iwo l'onibu ife
cr Fi igbala Re be w a wo
M'okan eru wa duro. - Wa, Olodumare, gba wa
Fun wa l'ore-ofe Re
L'ojiji ni k'opada wa,
Ma si fi wa sile mo;. - Iwo l'a o ma yin titi,
Bi won ti nse ni orun
Iyin w ki yoo lopin
A o s'ogo n'nu 'fe Re. - cr S'asepe awa eda Re
Je k'a wa lailabawon
K'a ri titobi 'gbala Re
Li aritan ninu Re. - Mu wa lat'ogo de ogo,
Titi de ibugbe wa;
T'ao fi ade wa juba Re
N'iyanu, ife, iyin.
Amin.