SI O OLUTUNU ORUN LYRICS
- Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya - Si O, ife eni t’Owa
Ninu Majemu Olorun
A nko, Aleluya - Si O agbara Eni ti
O nwe ni mo, t’o nwo ni san
A nko, Aleluya - Si O, Oluko at’ore
Amona wa toto d’opin
A nko, Aleluya. - Si O, Eniti Kristi ran
Ade on gbogbo ebun re
A nko, Aleluya. Amin.